KINI A NPE NI KADARA ATI AYANMỌ?
Kadara ni Ojo, Osu ati Odun ti Olukuluku wa wa sí aiye, ti ayanmọ sì je oruko ti won so wa olukuluku wa. Ninu imo Number ni a ti ri aridaju wipe Number ayanmọ ko gbodo wuwo koja number Kadara.
Ti onka Ayanmọ bá Tobi ju onka kádàrá lo eleyi le fa Ifaseyin nla fún eniti o ba ni iru idojukọ yìí. onka ayanmo ko gbodo tobiju kadara lo, bi onka ayanmo ba tobi ju kadara lo o wa da gegebi eniti won won weight re ti ko ju 45kg lo ti won wani ko gbe apo cement 100kg... kole si ilo siwaju to gun fun iru eda be laye, eniti o fe gbe apo cement duro gegebi kadara i.e 45kg ti apo cement duro fun ayanmo 100kg. Nidi eyii aye waa lati se ayipada Ayanmo, i.e apo cement pada si 30kg sugbon ko si aye ati yii eniti o fe gbe apo cement yii pada rara.
Afani wa pupo fún wa láti ṣe ayipada Ayanmọ sugbon kosi afani lati se ayipada kadara nitoripe Kadara Ko se yí padà mo.
Ninu Iwadi onka kádàrá ati ayanmọ ni ati le mo ako se jaiye eda, gegebi ohun ti ko gbodo ma se ati ohun ti o yẹ ki o ma se.
Bi àpèjúwe iru oúnjẹ, iru awo aṣọ rẹ̀, iru ojo orire rẹ, iru iyawo ti o le fẹ ati eyiti ko ṣọra fún lati fẹ. Iru Ise amun t'ọrun wa rẹ ati bebe lo.
Ọnà méjì ni a Pin eto yìí sì fún gbogbo awa oni ibere
1. Wiwo karada ati ako se jaiye
2. Wiwo igbeyawo larin Okunrin ati Obinrin
KINI OHUN TI A MA FI SE ÌWÁDÌÍ KÁDÀRÁ ATI AKO SE JAIYE WỌN YII?
1. Oruko ti a nje
2. Ojo ibi wa e.g 13/10/1920
KINI AMA NFI NSE ÌWÁDÌÍ IGBEYAWO
1. Oruko ololufe mejeji pelu oruko iya won
2. Ojo, osu ati odun ti a bi awon mejeji. E.g
13- oct- 1990
or
10-oct-2000
please do not write 10-10-2000 or 1-5-2000
No comments:
Post a Comment