Tuesday, April 5, 2022

AWEBI WEPE DANU

 Eso aworonso, ata ijosi meje ao lopo pelu epo obo die o wa po mo ose dudu ti a le we fun ojo meta ao fi epo para lale ni dede agogo mejila oru ao we eyokan ninu ose naa tobadi ojo keji ao fi ori para ao we tobadi ojo keta ao fi oyin para ao we..


keyinkeyin ototo ni a ma fi we iwe yii o ao gbodo lo keyinkeyin eyokan fun ose meteta rara o. ale ni dede agogo mejila oru ni wiwe re.

Monday, April 4, 2022

AGBO IBA TYPHOD TODAJU

 Alubosa onisu funfun toba Tobi dada mẹta ao ge kekeke sinu ike nla kan ao ko ewe Eyinolobe tutu le lórí dada ao wa da 7up le lórí dada ao gbe pamo fún ojó méta leyin ojo keta ejeki a ma mun diedie lojojumo ki a ma fún àwọn ọmọ wa mun nibe o dara pupo. Dr Mutiu Olatiboye

Sunday, April 3, 2022

ASEJE ASINA

 Ao lo si ibi ti efo gure bawa ao ja ti aba ti fe ja ao ma pe ni efo gburo mi ao ma ja ao wa re gegebi a se ma nre efo jije ao wa ponmo kika ao gesi meje tabi iyekiye ao fi se efo yen je pelu ponmo naa ao wa eko elewe kan ao fi je sugbon ki ato je so so wipe asiri eko ki tu loju ewe ki asiri emi lagbaja omo lagbaja ma se tu loji omo araiye ao je