Alubosa onisu funfun toba Tobi dada mẹta ao ge kekeke sinu ike nla kan ao ko ewe Eyinolobe tutu le lórí dada ao wa da 7up le lórí dada ao gbe pamo fún ojó méta leyin ojo keta ejeki a ma mun diedie lojojumo ki a ma fún àwọn ọmọ wa mun nibe o dara pupo. Dr Mutiu Olatiboye
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
-
Owo je unkan pataki ti o ye ki a ma mun rin lekokan tabi nigba gbogbo, ninu ogun to kereju fun omo Yoruba lati ma fi si ara o yeki Owo je o...
-
JU OGO MI SILE Ejeki awa ewé túdè ati egbo túdè, epo obo ti o fe to atelewo eniti o fe se iṣẹ náà ti aba fe se fún enia ama so fun ẹni náà ...
-
ELEYI NI ASIRI TI A NFI NGBA ORE WA PADA LOWO AWON ALA IRU EDA. Ejeki awa ewe gbegbe tutu, ewe Imi Esu tutu ao gun kuna dada pẹlu epo obo ...
Thank you very much for sharing this information
ReplyDelete